Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
‘‘Ó ń bọ̀, ó ń bọ̀!’’ la fi ń dẹ́rù ba ọmọdé; bó bá dé tán ẹ̀rù a tán.
1
Atorọjẹ 'ò lè gbọn tó ẹni fún un lóńje je.
1
Olúkàrẹ́ ti ìlú Ìkàrẹ́ Àkókó ń jẹ́ ẹjọ́ lọ́wọ́ lọ́dọ̀ ìjọba lórí ìgbésẹ̀ tí ó gbé.
0
Ẹnikan l'ó parí l'Ợìn ni gbogbo ara Ọmìn dapárí.
1
Àgbà-dídà kọ ni wọn fi ń jẹ “Fadá.”
1
Atọmọ ẹkùn, àtọmọ ajá, wọn ò tọmọ Kiniun.
1
Àwọn èèyàn kan mọ̀ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
0
Ìpele kẹrin ni akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n gún lọ́bẹ pa wà.
0
Bó bá kuni ku iti-ogede k'eni má wulę yáná.
1
A-gbé-ọ̀ọ̀dẹ̀ bí òfé, a-mọ-ara-í-ré bí oódẹ; a dẹ́bọ fún òfé, òfé ò rú, agánrán gbẹ́bọ, ó rúbọ; àsẹ̀hìnwá àsẹ̀hìnbọ̀ òfé di ará Ọ̀yọ́, agánrán di ará oko; wọ́n rò pé òfé ò gbọ́n.
1
Bísó ọmọ ò rún, ìyà a fi tię sejo e.
1
Gbogbo Òrisà n'lfá ń kì fún, kó s'Óòșà tí ó ń kì fún lfá.
1
Erin ń lọ lóko, àgbẹ ń tàka, erìn kọjá ẹran àń fọkòó pa.
1
B'íyàwó ọlẹ dàgbà tán, olówó níí fẹ ẹ.
1
Àgbà òṣìkà ń gbin ìyà sílẹ̀ de ọmọ-ọ rẹ̀.
1
Ara kì í wúwo kí alára má lè gbe.
1
Bí ọmọdé bá ní baba òun ò tó ẹni tí à ń sáré bá, bàbá-a rẹ̀ a ní ọmọ òun ò tó ẹni tí à ń dúró dè.
1
Àjẹ́ ké lánàá, ọmọ́ kú lónìí; ta ni ò mọ̀ pé àjẹ́ àná ló pọmọ jẹ?
1
Àròkàn àròkàn ní ń fa ẹkún àsun-ǹ-dá.
0
Kò gbọdọ̀ sí awúrúju nínú iṣẹ́ tó wà nílẹ̀.
0
Àtẹ́lẹwọ́ ò ṣéé fi rúná.
1
Olóṣèlú ìlú Ìbàdàn ni Ògúnrónbí Ajétúnmọbí.
0
Àwúrèbeé ní òun lè yẹ̀nà; ta ní jẹ́ tọ ọ̀nà àwúrèbe?
1
Àgékù ejò, tí ń ṣoro bí agbọ́n.
1
Ọláyínká ní òun mọ̀ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
0
‘‘Mo mọ̀-ọ́ gùn’’ lẹṣin ń dà.
1
Àkọ̀ tó bá bá ọ̀bẹ dìtẹ̀ á gbọgbẹ́ láti inú.
1
Awuyewuye ń jẹyọ láàárín ìjọba àtàwọn ará ìlú nígbà tí wọ́n kéde kíkọ́ ọ̀nà Ẹlẹ́bú.
0
B'áyé irun bá bàjẹ (díjú) òòyà níí yanjú ẹ.
1
Fúnra ra Agílíńtí ló ń gbe ara e wónlẹ.
1
Ó jọ èyí tí ó rọrùn ni ṣùgbọ́n kò rọrùn rárá.
0
Ìtọ́jú àyíká ṣe pàtàkì púpọ̀ bí oúnjẹ jíjẹ ṣe jẹ́ ọ̀ran-an-yàn.
0
B'érin bá kù, a fitẹ sílẹ.
1
B'ọmọdé ba dọgbọn kú, àwọn àgbà a sì dọgbọn sin ín.
1
Bọ́lá di èrò ẹ̀wọ̀n ní ìlú òkèèrè.
0
Àgbásí mú ààtàn gélé.
1
Dọ́kítà ti kọ àwọn ògùn fún mi.
0
Ohun tí ó kan ẹlòmíràn nínú àwọn olùkọ́ kò ju owó oṣù tí wọ́n ń gbà lọ.
0
A parí ìjà wa lálẹ́ ọjọ́ náà lẹ́yìn tí àwọn aládùúgbò dá sí i.
0
A di gàárì sílẹ̀ ewúrẹ ń yọjú; ẹrù ìran rẹ̀ ni?
1
Mo bẹ obìnrin yẹn kó tó kú nígbà tí mo ti ibiṣẹ́ dé.
0
Adígbọ́nránkú ń fikú ṣeré.
1
B'éèyàn bá n tan'ra e je, ó sì le è yó, béèyàn bá ń tan ara re danù ló burú jù. (pin)
1
Wọ́n bá òkú ọkùnrin náà níbi tó ti ń rọ́ lábẹ́ igi.
0
Àgbọ́ká etí ọlọ́ràn á di.
1
Àwọn agbófinró mìíràn wà nítòsí láti gbèjà akẹgbẹ́ wọn.
0
Àgbà-ì-kà lolè ń gbowó.
1
Ẹgbẹ́ jàǹdùkú ti ní orúkọ tuntun.
0
Bí oyun ṣe máa ń ṣe aláboyún máa ń yàtọ̀ síra wọn.
0
A kì í gbélé mọ ogun tí ò níí dùn.
1
Ẹ̀mílójù sọ wí pé kí wọ́n ṣe òun jẹ́jẹ́ nígbà tí wọ́n fi ọwọ́ òfin mú un.
0
Àjọ tó ń mójútó ètò ìnáwó kéde orúkọ àwọn oníṣòwò Dọ́là.
0
Ó ti tó ọdún mẹ́ta tí Bíọ́lá àti ọkọ rẹ̀ Olúwaṣèyí ti ṣègbéyàwó.
0
Ẹni tí 'ò fẹràn ẹni, a ì í pé kó fejú fún ni.
1
Bí Șàngó bá pawo, ilẹ ló dà.
1
Dòsùnmú ní àwọn ní àwọn dọ́kítà tó kójú òṣùwọ̀n ní iléèwòsàn àwọn.
0
Wọn yóò gbà wá nímọ̀ràn lórí ohun tí a lè ṣe tí a kò fi ní máa yáwó.
0
Ẹní bẹ nì, te ni.
1
B'ó bá ku awẹ (aye) idí kan, ọmọ ni k'á fi bí.
1
Aṣọ tí yóò ya níí rẹrìn-ín abẹrẹ.
1
Ọwọ́ ba àwọn afurasí mẹ́rin tó jí kẹ̀kẹ́ gbé látàrí ìtọpinpin ẹ̀ṣọ́ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́.
0
Iléeṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin ti fi páńpẹ́ òfin gbé Ajíṣafẹ́.
0
À bá mọ̀ a kò ṣe é; a ṣé tán ó di aápọn.
1
Abẹ́rẹ́ bọ́ sómi táló; Ọ̀dọ̀fín ní òun-ún gbọ́ ‘‘jàbú!’’
1
Bí iná bá dun ọbẹ̀, a dá ọ̀rọ̀ sọ.
1
Àjímú kì í tí.
1
Lẹ́yìn èyí ni Oríyọmí di àyẹ̀wé-owó fún ilé iṣẹ́ búrẹ́dì ní ọdún tó lọ.
0
A kì í rí kékeré ẹkùn.
1
Atúnniṣe ò pọ̀ bí abanijẹ́ .
1
Àpòjù iyọ̀ nínú óúnjẹ maa ń fa àìsàn nínú àgọ-ara.
0
Akínwándé ní inú ara wọn ni àwọn ìyókù ń dù.
0
Bíná 'ò bá tán l'órí; ejẹ 'ò leé tán léèkànná.
1
Àwọn eléré orí ìtàgé elédè Yorúbà náà sọ̀rọ̀.
0
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń tọ́jú ọgbẹ́ lásìkò yìí lè jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹlẹ́gírí tí ọta ìbọn bà.
0
Ayòdélé ní ọwọ́ pálábá Sàlàkọ́ Kúforíjì yóò ségi lọ́dún tuntun
0
Bí kò sí tọmú tí ḿbẹ láyà obìnrin, tí kò sí ìlẹ̀kẹ̀ tí ḿbẹ nídìí àgbèrè, ọ̀rẹ́ -ẹ̀ mí dára díẹ̀ ju obìnrin lọ.
1
Bí a bá ń gúnyán, kòmẹsẹ̀ á yọ.
1
À-rí-ì-gbọdọ̀-wí, à-rí-ì-gbọdọ̀-fọ̀ ni ikú awo.
1
Ó ti wá hàn gbangba gbàǹgbà báyìí pé ọmọ náà ti di èrò ọ̀run àpàpàǹdodo.
0
Mo fẹ́ràn àyíká tó ṣeé gbé tí kò sì láriwo.
0
Áásìkí tí a fún ẹyẹ ọ̀sìn a ò fún igún; áásìkí ẹrú ò sí lọ́dọ̀ ọmọ.
1
Ahọ́n ni ìpínnlẹ̀ ẹnu.
1
·Eni fori wéri, á jopo lyà. Orin ti Láwáreko to tó gba orekese n ni Láwre
1
Ẹgbẹ́ jàǹdùkú pa arákùnrin kan torí ó fi ojú diwọ́n.
0
A gbọ́ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ pé òkú ọkùnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínláàdọ́rún pòórá.
0
Àwọn ọlọ́pàá ti ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn àwòrán tó wà lọ́wọ́ wọn.
0
Àìsàn ibà ti wọ ìlú wa, ó sì ti ń mú tọmọdé tàgbà.
0
Eșú tó jẹ yangan ló 'kó aápọn bá ișu (báșu).
1
Bí ìlùú bá dún àdúnjù, yó fàya.
1
Bí Ọya ń kọ lọ́run, bí Ṣàngó ń jó láyé, kò níí burú fún baba kó ní ó dọwọ́ ọmọ òun lọ́run.
1
Agbègbè Sángo ní ìlú Ìbàdàn ni ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún ti wáyé.
0
Gbogbo oko làá fi ń jin ewújù.
1
Ẹnu kì í ká alásejù.
1
Bín-índùn, k'à máa fura.
1
Àilówó l'ẹbí 'ò sí; owó làgbà.
1
Àjọrìn ní ń yẹ èrò.
1
Baálẹ̀ kọ́ lọ́ ṣe ètò ìrànwọ́ ìwé kíkà fún àwọn ọmọ ìlú.
0
Ajé torí èrè rojà.
1
Dansoman àti Túbá wà ní orílẹ̀-èdè Gánà.
0
Afọ́jú tó dijú, tó ní òun sùn, ìgbàtí kò sùn ta ló rí?
1